Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 5:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wá pa òwe kan fún wọn pé, “Kò sí ẹni tí ó jẹ́ ya lára ẹ̀wù titun kí ó fi lẹ ògbólógbòó ẹ̀wù. Bí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀, ó ti ba ẹ̀wù titun jẹ́, aṣọ titun tí ó sì fi lẹ ògbólógbòó ẹ̀wù kò bá ara wọn mu.

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:36 ni o tọ