Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 5:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan sọ fún un pé, “Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu ń gbààwẹ̀ nígbà pupọ, wọn a sì máa gbadura. Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àwọn Farisi. Ṣugbọn àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ ń jẹ, wọ́n ń mu ní tiwọn ni.”

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:33 ni o tọ