Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 5:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Farisi ati àwọn amòfin tí wọ́n wà ninu ẹgbẹ́ wọn wá ń kùn sí Jesu. Wọ́n bi í pé, “Kí ló dé tí o fi ń bá àwọn agbowó-odè ati àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ jẹ, tí ò ń bá wọn mu?”

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:30 ni o tọ