Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan nígbà tí Jesu wà ninu ìlú kan, ọkunrin kan tí ẹ̀tẹ̀ bò ní gbogbo ara rí i. Ó bá wá dojúbolẹ̀, ó ń bẹ̀ ẹ́ pé, “Alàgbà, bí o bá fẹ́, o lè sọ ara mi di mímọ́.”

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:12 ni o tọ