Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya Jakọbu náà ati Johanu, àwọn ọmọ Sebede, tí wọ́n jẹ́ ẹlẹgbẹ́ Simoni. Jesu wá sọ fún Peteru pé, “Má bẹ̀rù. Láti ìgbà yìí lọ eniyan ni ìwọ yóo máa mú wá.”

Ka pipe ipin Luku 5

Wo Luku 5:10 ni o tọ