Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn ni wọ́n gbà fún un, ẹnu sì yà wọ́n fún ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ tí ó ń sọ jáde, wọ́n wá ń sọ pé, “Àbí ọmọ Josẹfu kọ́ nìyí ni?”

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:22 ni o tọ