Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ̀mí Oluwa wà pẹlu minítorí ó ti fi òróró yàn míláti waasu ìyìn rere fún àwọn talaka.Ó rán mi láti waasu ìtúsílẹ̀fún àwọn tí wọ́n wà ní ìgbèkùn,ati láti mú kí àwọn afọ́jú ríran;láti jẹ́ kí àwọn tí a ni lára lọ ní alaafia,

Ka pipe ipin Luku 4

Wo Luku 4:18 ni o tọ