Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá ń kiri gbogbo ìgbèríko odò Jọdani, ó ń waasu pé kí àwọn eniyan ronupiwada, kí wọ́n ṣe ìrìbọmi, kí Ọlọrun lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì wọ́n.

Ka pipe ipin Luku 3

Wo Luku 3:3 ni o tọ