Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Johanu sọ fún gbogbo eniyan pé, “Omi ni èmi fi ń ṣe ìwẹ̀mọ́ fun yín, ṣugbọn ẹni tí ó jù mí lọ ń bọ̀. Èmi kò tó ẹni tíí tú okùn bàtà rẹ̀. Ẹ̀mí Mímọ́ ati iná ni yóo fi wẹ̀ yín mọ́.

Ka pipe ipin Luku 3

Wo Luku 3:16 ni o tọ