Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹẹdogun tí Ọba Tiberiu ti wà lórí oyè, nígbà tí Pọntiu Pilatu jẹ́ gomina Judia, tí Hẹrọdu jẹ́ baálẹ̀ Galili, tí Filipi arakunrin rẹ̀ jẹ́ baálẹ̀ Ituria ati ti agbègbè Tirakoniti, Lusaniu jẹ́ baálẹ̀ Abilene;

Ka pipe ipin Luku 3

Wo Luku 3:1 ni o tọ