Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kúrò ní ibojì náà, wọ́n pada lọ sọ gbogbo nǹkan tí wọ́n rí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mọkanla ati gbogbo àwọn yòókù.

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:9 ni o tọ