Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:52-53 BIBELI MIMỌ (BM)

52. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn júbà rẹ̀, wọ́n bá fi ọpọlọpọ ayọ̀ pada lọ sí Jerusalẹmu.

53. Inú Tẹmpili ni wọ́n ń wà nígbà gbogbo, tí wọ́n ń fi ìyìn fún Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luku 24