Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn kò gbàgbọ́ sibẹ nítorí pé ó yà wọ́n lẹ́nu ati pé wọn kò rí bí ó ti ṣe lè rí bẹ́ẹ̀, ó bi wọ́n pé, “Ṣé ẹ ní nǹkan jíjẹ níhìn-ín?”

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:41 ni o tọ