Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wo ọwọ́ mi ati ẹsẹ̀ mi, kí ẹ rí i pé èmi gan-an ni. Ẹ fọwọ́ kàn mí kí ẹ rí i, nítorí iwin kò ní ẹran-ara ati egungun bí ẹ ti rí i pé mo ní.”

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:39 ni o tọ