Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá ń bá ara wọn sọ pé, “Ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú wa lọ́kàn bí ó ti ń bá wa sọ̀rọ̀ lọ́nà, ati bí ó ti ń túmọ̀ Ìwé Mímọ́ fún wa!”

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:32 ni o tọ