Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu wọn tí ń jẹ́ Kilopasi dá a lóhùn pé, “Ṣé àlejò ni ọ́ ní Jerusalẹmu ni, tí o kò fi mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ níbẹ̀ ní ààrin bí ọjọ́ mélòó kan yìí?”

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:18 ni o tọ