Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní kutukutu òwúrọ̀ ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, wọ́n wá sí ibojì, wọ́n mú òróró olóòórùn dídùn tí wọ́n ti tọ́jú lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Luku 24

Wo Luku 24:1 ni o tọ