Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:56 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá pada lọ láti lọ tọ́jú turari olóòórùn dídùn ati ìpara tí wọn fi ń tọ́jú òkú.Ní Ọjọ́ Ìsinmi, wọ́n sinmi gẹ́gẹ́ bí òfin ti wí.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:56 ni o tọ