Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ òkú náà kalẹ̀ lórí agbelebu, ó fi aṣọ funfun wé e, ó bá tẹ́ ẹ sinu ibojì tí wọ́n gbẹ́ sinu àpáta, tí wọn kò ì tíì tẹ́ òkú sí rí.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:53 ni o tọ