Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:50-51 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ninu àwọn ìgbìmọ̀ tí ó ń jẹ́ Josẹfu. Ó jẹ́ eniyan rere ati olódodo. Òun kò bá wọn lóhùn sí ète tí wọ́n pa, ati ohun tí wọ́n ṣe sí Jesu. Ó jẹ́ ará Arimatia, ìlú kan ní Judia. Ó ń retí ìjọba Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:50-51 ni o tọ