Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan dúró, wọ́n ń wòran. Àwọn ìjòyè ń fi í ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n ń sọ pé, “O gba àwọn ẹlòmíràn là; gba ara rẹ là bí ìwọ bá ni Mesaya, àyànfẹ́ Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:35 ni o tọ