Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí fi ẹ̀sùn kàn án pé, “A rí i pé ńṣe ni ọkunrin yìí ń ba ìlú jẹ́. Ó ní kí àwọn eniyan má san owó-orí. Ó tún pe ara rẹ̀ ní Mesaya, Ọba.”

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:2 ni o tọ