Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 23:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Hẹrọdu náà kò rí nǹkankan wí sí i, nítorí ńṣe ni ó tún dá a pada sí wa. Ó dájú pé ọkunrin yìí kò ṣe nǹkankan tí ó fi yẹ kí á dá a lẹ́bi ikú.

Ka pipe ipin Luku 23

Wo Luku 23:15 ni o tọ