Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 22:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ta ni eniyan pataki? Ẹni tí ó jókòó tí ó ń jẹun ni, tabi ẹni tí ó ń ṣe iranṣẹ? Mo ṣebí ẹni tí ó ń jẹun ni. Ṣugbọn èmi wà láàrin yín bí ẹni tí ó ń ṣe iranṣẹ.

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:27 ni o tọ