Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 22:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni wọ́n bá lọ, wọ́n rí ohun gbogbo bí Jesu ti sọ fún wọn. Wọ́n sì tọ́jú gbogbo nǹkan fún àsè Ìrékọjá.

Ka pipe ipin Luku 22

Wo Luku 22:13 ni o tọ