Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí èmi fúnra mi ni n óo fi ọ̀rọ̀ si yín lẹ́nu, n óo sì fun yín ní ọgbọ́n tí ó fi jẹ́ pé ẹnikẹ́ni ninu gbogbo àwọn tí ó lòdì si yín kò ní lè kò yín lójú, tabi kí wọ́n rí ohun wí si yín.

Ka pipe ipin Luku 21

Wo Luku 21:15 ni o tọ