Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 20:31-33 BIBELI MIMỌ (BM)

31. Ẹkẹta náà ṣú u lópó. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn mejeeje ṣe, wọ́n kú láì ní ọmọ.

32. Ní ìgbẹ̀yìn-gbẹ́yín, obinrin náà alára wá kú.

33. Ní ọjọ́ ajinde, ti ta ni obinrin náà yóo jẹ́, nígbà tí ó jẹ́ pé àwọn mejeeje ló ti fi ṣe aya?”

Ka pipe ipin Luku 20