Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 20:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bi í pé, “Olùkọ́ni, a mọ̀ pé tààrà ni ò ń sọ̀rọ̀, tí o sì ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́. O kì í wo ojú eniyan kí o tó sọ̀rọ̀. Ṣugbọn pẹlu òtítọ́ ni ò ń kọ́ eniyan ní ọ̀nà Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luku 20

Wo Luku 20:21 ni o tọ