Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 2:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn òbí rẹ̀ rí i, ẹnu yà wọ́n. Ìyá rẹ̀ bá bi í pé, “Ọmọ, kí ló dé tí o fi ṣe wá báyìí? Èmi ati baba rẹ dààmú pupọ nígbà tí à ń wá ọ.”

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:48 ni o tọ