Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ní Jerusalẹmu tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Simeoni. Ó jẹ́ olódodo eniyan ati olùfọkànsìn, ó ń retí àkókò tí Ọlọrun yóo tu Israẹli ninu. Ẹ̀mí Mímọ́ wà pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:25 ni o tọ