Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí àwọn angẹli náà ti pada kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ọ̀run, àwọn olùṣọ́-aguntan ń sọ láàrin ara wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ sí Bẹtilẹhẹmu tààrà, kí á lè rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀, tí Oluwa bùn wá gbọ́.”

Ka pipe ipin Luku 2

Wo Luku 2:15 ni o tọ