Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 19:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó súnmọ́ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Olifi, ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fi ayọ̀ kígbe sókè, wọ́n ń yin Ọlọrun nítorí gbogbo ohun ńlá tí wọ́n ti rí.

Ka pipe ipin Luku 19

Wo Luku 19:37 ni o tọ