Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí abúlé tí ó wà ní ọ̀kánkán yìí. Nígbà tí ẹ bá wọ ibẹ̀, ẹ óo rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí wọ́n so mọ́lẹ̀, tí ẹnikẹ́ni kò gùn rí. Ẹ tú u, kí ẹ fà á wá.

Ka pipe ipin Luku 19

Wo Luku 19:30 ni o tọ