Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu gbọ́, ó sọ fún un pé, “Nǹkankan ló kù ọ́ kù. Lọ ta gbogbo ohun tí o ní, kí o pín owó rẹ̀ fún àwọn talaka, ìwọ yóo wá ní ìṣúra ní ọ̀run. Kí o máa wá tọ̀ mí lẹ́yìn.”

Ka pipe ipin Luku 18

Wo Luku 18:22 ni o tọ