Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọkunrin kán wà tí ó lówó. Aṣọ àlàárì ati àwọn aṣọ olówó iyebíye mìíràn ni ó máa ń wọ̀. Oúnjẹ àdídùn ni ó máa ń jẹ, lojoojumọ ni ó máa ń se àsè.

Ka pipe ipin Luku 16

Wo Luku 16:19 ni o tọ