Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá sọ fún wọn pé, “Ẹ̀yin ni ẹ̀ ń dá ara yín láre lójú eniyan, ṣugbọn Ọlọrun mọ ọkàn yín. Ohun tí eniyan ń gbé gẹ̀gẹ̀, ohun ẹ̀gbin ni lójú Ọlọrun.

Ka pipe ipin Luku 16

Wo Luku 16:15 ni o tọ