Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sọ fun yín, bẹ́ẹ̀ gan-an ni, ayọ̀ tí yóo wà ní ọ̀run nítorí ẹlẹ́ṣẹ̀ kan tí ó ronupiwada ju ti ìtorí àwọn olódodo mọkandinlọgọrun-un tí kò nílò ìrònúpìwàdà lọ.

Ka pipe ipin Luku 15

Wo Luku 15:7 ni o tọ