Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ọkunrin kan bá ní ọgọrun-un aguntan tí ọ̀kan sọnù ninu wọn, ṣé kò ní fi mọkandinlọgọrun-un yòókù sílẹ̀ ní pápá, kí ó wá èyí tí ó sọnù lọ títí yóo fi rí i?

Ka pipe ipin Luku 15

Wo Luku 15:4 ni o tọ