Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 15:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ojú rẹ̀ wálẹ̀, ó ní, ‘Àwọn alágbàṣe baba mi tí wọn ń jẹ oúnjẹ ní àjẹṣẹ́kù kò níye. Èmi wá jókòó níhìn-ín, ebi ń pa mí kú lọ!

Ka pipe ipin Luku 15

Wo Luku 15:17 ni o tọ