Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 12:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba yóo lòdì sí ọmọ, ọmọ yóo lòdì sí baba. Ìyá yóo lòdì sí ọmọ rẹ̀ obinrin, ọmọbinrin yóo lòdì sí ìyá rẹ̀. Ìyakọ yóo lòdì sí iyawo ilé, iyawo ilé yóo lòdì sì ìyakọ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:53 ni o tọ