Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ẹni tí ẹ̀ bá bẹ̀rù hàn yín. Ẹ bẹ̀rù ẹni tí ó jẹ́ pé nígbà tí ó bá pa ara tán, ó ní àṣẹ láti tún sọ eniyan sinu ọ̀run àpáàdì. Mo sọ fun yín, ẹ bẹ̀rù olúwarẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:5 ni o tọ