Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 12:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹrú tí oluwa wọn bá dé, tí ó bá wọn, tí wọn ń ṣọ́nà, ṣe oríire. Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé, yóo di ara rẹ̀ ní àmùrè, yóo fi wọ́n jókòó lórí tabili, yóo wá gbé oúnjẹ ka iwájú wọn.

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:37 ni o tọ