Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ mọ̀ pé ohunkohun tí ẹ sọ ní ìkọ̀kọ̀, a óo gbọ́ nípa rẹ̀ ní gbangba. Ohun tí ẹ bá sọ ninu yàrá, lórí òrùlé ni a óo ti pariwo rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:3 ni o tọ