Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí wọ́n bá mu yín lọ sinu ilé ìpàdé ati siwaju àwọn ìjòyè ati àwọn aláṣẹ, ẹ má ṣe dààmú nípa bí ẹ óo ti ṣe wí àwíjàre tabi pé kí ni ẹ óo sọ.

Ka pipe ipin Luku 12

Wo Luku 12:11 ni o tọ