Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ọ̀rẹ́ náà wá ti inú ilé dáhùn pé, ‘Má yọ mí lẹ́nu. Mo ti ti ìlẹ̀kùn, àwọn ọmọ mi sì wà lórí ẹní pẹlu mi, n kò lè tún dìde kí n fún ọ ní nǹkankan mọ́.’

Ka pipe ipin Luku 11

Wo Luku 11:7 ni o tọ