Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà kan, Jesu wà níbìkan, ó ń gbadura. Nígbà tí ó parí, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ fún un pé, “Oluwa, kọ́ wa bí a ti í gbadura gẹ́gẹ́ bí Johanu ti kọ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.”

Ka pipe ipin Luku 11

Wo Luku 11:1 ni o tọ