Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ilé kan náà ni kí ẹ máa gbé. Ohun tí wọ́n bá gbé kalẹ̀ fun yín ni kí ẹ máa jẹ, kí ẹ sì máa mu. Owó iṣẹ́ alágbàṣe tọ́ sí i. Ẹ má máa lọ láti ilé dé ilé.

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:7 ni o tọ