Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu bá dá a lóhùn pé, “Ọkunrin kan ń ti Jerusalẹmu lọ sí Jẹriko, ni ó bá bọ́ sí ọwọ́ àwọn ọlọ́ṣà. Wọ́n gba aṣọ lára rẹ̀, wọ́n lù ú, wọ́n bá fi í sílẹ̀ nígbà tí ó fẹ́rẹ̀ kú tán.

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:30 ni o tọ