Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dáhùn pé, “Kí ìwọ fẹ́ràn Oluwa Ọlọrun rẹ pẹlu gbogbo ọkàn rẹ, ati pẹlu gbogbo ẹ̀mí rẹ, ati pẹlu gbogbo agbára rẹ ati pẹlu gbogbo òye rẹ; sì fẹ́ràn ọmọnikeji rẹ bí ara rẹ.”

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:27 ni o tọ