Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 9:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo bá wà láàrin àwọn aláìlera, èmi a di aláìlera, kí n lè jèrè àwọn aláìlera. Èmi a máa sọ ara mi di gbogbo nǹkan fún gbogbo eniyan, kí n lè gba àwọn kan ninu wọn là lọ́nà kan tabi lọ́nà mìíràn.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 9

Wo Kọrinti Kinni 9:22 ni o tọ